Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ọgọrin eeyan ti sa kuro lakata ajinigbe ninu olujọsin mẹtadinlọgọsan ti wọn ji gbe ni ṣọọṣi mẹta ni Kaduna.
Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa Kaduna, DSP Mansur Hassan, fidi eyi mulẹ fun BBC.
O ni ọjọ ti wọn ti ji wọn gbe ni wọn ti sa lasiko tawọn ajinigbe naa n ko wọn kiri.
Awọn wo lo wa ku nigbekun?
Ẹkunrẹrẹ wa ni BBC.COM/Yoruba
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ijóba Kwara paṣẹ ki wọn ṣi awọn ile ẹkọ ti wọn tipa lọdun to kọja nitori aabo.
Kọmiṣanna eto ẹkọ ni Kwara, Lawal Olohungbebe, ninu atẹjade rẹ sọ pe oni ọjọ Aje ni igbẹkọ bẹrẹ.
Lẹyin ti wọn ti awọn ile ẹkọ naa pa nitori ikọlu sile ijọsin, jiji ọpọ eeyan gbe ati pipa awọn mi-in.
Ṣe aabo to peye ti wa ni Kwara bayii ni?
lllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll
Wọn ti gbe oku Ifunanya Nwangene, ọmọbinrin olorin ti ejo pa l'Abuja lọ si ilu rẹ l'Enugu.
Gẹgẹ bi baba rẹ ṣe ni ki wọn gbe e wa.
Satide ijẹta ni ejo ṣan an ninu yara rẹ.
Ko si ri aporo gba nileewosan meji to fi ku



